Ọkọ́ rẹ̀ kúrú jù.
Lia rastro estis tro mallonga.
Ọ̀nà ilẹ̀kùn rẹ̀ kéré jù.
Lia pordaperturo estis tro malalta.
Ibùsùn rẹ̀ kúrú jù.
Lia lito estis tro mallonga.
Kẹ̀kẹ́ rẹ̀ kúrú jù.
Lia biciklo estis tro malgranda.
Ọkùnrin yìí ga jù!
Tiu ĉi homo estis tro alta!
Ó ṣe ọwọ ọkọ́
gígùn púpọ̀ kan.
Li faris tre longan tenilon por sia rastro.
Ó ṣe ara ilẹ̀kùn
gíga púpọ̀.
Li faris tre altan pordaperturon.
Ó ṣe ibùsùn
gígùn púpọ̀ kan.
Li faris tre longan liton.
Ó ra kẹ̀kẹ́
gíga púpọ̀ kan.
Li aĉetis tre altan biciklon.
Ó jòkó lórí aga
gíga kan.
Ó jẹun pẹ̀lú fọ́ọ̀kì
gígùn kan.
Li sidis sur tre alta seĝo. Li manĝis per tre longa forko.
Ó kúrò ní ilé rẹ̀,
o sì gbé ní igbó
ńlá kan.
Ó gbé fún ọdún púpọ̀.
Li forlasis sian domon kaj translokiĝis al granda arbaro. Li loĝis tie dum multaj jaroj.